|
Do you know anyone who is employed on the US facility? |
|
|
shay o mo eh nee yaH ko ko tee o ohn shee sheh nee ee bee o on ee nee aamee ree ka? |
|
Ṣé o mọ ènìyàn kankan tí ó n ṣiṣẹ́ ní ibi ohun ìní Amẹ́ríkà? |
|
|
Do you know of anyone who works with US forces who has participated in anti-US, anti-coalition, or anti-government protests? |
|
|
shay o mo ee nee yaH ko ko tee o ohn shee sheh fU awoH o mo o gU aamee ree ka tee o tee nee Pi nee no awoH eh to ee bee no aa oo nee Ba fU aamee ree ka, ee jo ba o ree leh eh day yee aa tee aa jay jee? |
|
Ṣé o mọ ènìyàn kankan tí ó n ṣiṣẹ́ fún àwọn ọmọ ogun Amẹ́ríkà tí ó ti níìpín nínú àwọn ètó ìbínú a-ò-nígbà fún Amẹ́ríkà, ìjọba orílẹ̀ èdè yì í àti àjèjì? |
|
|
Do you know anyone who is employed on the US facility that has expressed dislike or displeasure toward the US or coalition forces? |
|
|
shay o mo ee nee yaH ko ko tee o ohn shee sheh fU awoH o mo o gU aamee ree ka tee o tee soo roo ee kU see no nee Pa aamee ree ka taa bee ee jo ba aa jay jee? |
|
Ṣé o mọ ènìyàn kankan tí ó n ṣiṣẹ́ fún àwọn ọmọ ogun Amẹ́ríkà tí ó ti sọ̀rọ̀ ìkùnsínú nípa Amẹ́ríkà tàbí ìjọba àjèjì? |
|
|
Do you know of anyone who works on a US facility that has been approached by an anti-US or anti-coalition group? |
|
|
shay o mo ee nee yaH ko ko tee ohn shee sheh fU awoH o mo o gU aamee ree ka tee eh Beh awoH tee o ohn soo roo ee kU see no nee Pa aamee ree ka taa bee ee jo ba aa jay jee ohn ba soo roo? |
|
Ṣé o mọ ènìyàn kankan tí ó n ṣiṣẹ́ fún àwọn ọmọ ogun Amẹ́ríkà tí ẹgbẹ́ àwọn tí ó n sọ̀rọ̀ ìkùnsínú nípa Amẹ́ríkà tàbí ìjọba àjèjì n bá sọ̀rọ̀? |
|