 |
What communicable diseases in the local population pose the greatest risk to visiting foreigners? |
 |
 |
kee nee awoH aa rU nee aBeBe yee tee o jeh ee woo ohn laa fU awoH a lay jo laa tee o ree leh ee day meeraH? |
 |
Kíni àwọn aàrùn ní agbègbè yì í tí ó jẹ́ ewu nlá fún àwọn àlejò láti orílẹ̀ èdè mìràn? |
 |
 |
What medical conditions are the most common cause of death in this area? |
 |
 |
kee nee ohn aa ee lay raa tee o on Pa awoH ee nee yaH joo nee aBeBe yee? |
 |
Kíni ohun àilera tí ó n pa àwọn ènìyàn jù ní agbègbè yì í? |
 |
 |
Who is the local physician in this area? |
 |
 |
taa nee do kee taa ee bee leh nee aBeBe yee? |
 |
Tani dókítà ìbílẹ̀ ní agbègbè yì í? |
 |
 |
Where is he located and how can I contact him? |
 |
 |
ee bo nee o waa aa tee Pay baa wo nee mo shay lay ree? |
 |
Ibo ni ó wà àti pé báwo ni mo ṣe lè rí i? |
 |
 |
What parasites exist in local food and water? |
 |
 |
awoH ko ko roo aa rU wo nee o wa nee no ohn jeh aa tee o mee ee bee leh? |
 |
Àwọn kòkòrò aàrùn wo ni ó wà nínú oúnjẹ àti omi ìbílẹ̀? |
 |
 |
What diseases infect newborn children? |
 |
 |
awoH aa rU wo nee o maan moo awoH o mo tUtU? |
 |
Àwọn aàrùn wo ni ó má a n mú àwọn ọmọ tuntun? |
 |
 |
What chemical residues or foreign substances exist in the environment and may contribute to illness? |
 |
 |
awoH kaa mee kaa lee taa bee ohn ko wo nee no a feh feh tee o lay fa aa ee lay raa? |
 |
Àwọn kẹ́míkàlì tàbí nkan wo nínú afẹ́fẹ́ tí ó lè fa àilera? |
 |
 |
What sexually transmitted diseases are common in the local populace? |
 |
 |
awoH aa rU aa to see wo nee o wo Poo nee aa rE awoH aa raa aBeBe yee? |
 |
Àwọn aàrùn àtọ̀sì wo ni ó wọ́pọ̀ ní àárín àwọn ará agbègbè yì í? |
 |
 |
What diseases infect local livestock? |
 |
 |
awoH aa rU wo nee o maan moo awoH eh roH oo sE? |
 |
Àwọn aàrùn wo ni ó má a n mú àwọn ẹran ọ̀sìn? |
 |
 |
What sanitation problems affect the local population? |
 |
 |
awoH ee daa moo wo nee o waa nee Pa o roo ee mo to to fU awoH aa raa aBeBe yee? |
 |
Àwọn ìdàmú wo ni ó wà nípa ọ̀rọ̀ ìmọ́tótó fún àwọn ará agbègbè yì í? |
 |