Get Instructions
main picture
Title Bar
Go To Main Menu Print Page PagePage Total next page
Play Button What area in ___ has a high crime rate? Play Button aBeBe wo nee o lay woo joo nee ___? Agbègbè wo ni ó l'éwu jù ní ___?
Play Button What area in ___ would you feel uncomfortable entering with your family? Play Button aBeBe wo nee o bey roo laa tee moo eh bee reh loo nee ___? Agbègbè wo ni o bẹ̀rù láti mú ẹbí rẹ lọ ní ___?
Play Button What areas of ___ are considered unsafe for Americans to enter? Why? Play Button awoH aBeBe wo nee o lay woo fU awoH aa raa aamee ree ka laa tee loo nee ___? nee to ree kee nee? Àwọn agbègbè wo ni ó l'éwu fún àwọn ará Amẹ́ríkà láti lọ ní ___? Nítorí kíni?
Play Button What organized crime elements exist in ___? Play Button awoH jaan do koo wo nee o waa nee ___? Àwọn jàndùkú wo ni ó wà ní ___?
Play Button What are the most common criminal acts committed in ___? Play Button awoH aa shaa jaan do koo wo nee o Poo joo nee ___? Àwọn àṣà jàndùkú wo ni ó pọ̀jù ní ___?
Play Button What illegal substances are available in this area? Play Button awoH ohn ko bee ee Bo mee moo wo nee o waa nee aBeBe yee? Àwọn nkan bí i igbó mímu wo ni ó wà ní agbègbè yì í?
Play Button How are the drugs transported into this area? Play Button baa wo nee woH shay ohn Be ee Bo wo aBeBe yee? Báwo ni nwọ́n ṣe ngbé igbó wọ agbègbè yì í?
Play Button Who controls the sale of these drugs? Play Button taa nee o loo daa ree o wo ee Bo tee taa yee? Tani olùdarí òwò igbó títà yì í?
Play Button Is local law enforcement capable of dealing with the current criminal threat? Play Button shay awoH o loo Paa ee bee leh kaa Paa a kee tee yaH jaan do koo yee? Ṣé àwọn ọlọ́ọ̀pá ìbílẹ̀ k'ápá akitiyan jàndùkú yì í?
Play Button If not, what specific areas is local law enforcement unable to control? Play Button tee ko baa jeh beh, awoH a kee tee yaH jaan do koo wo nee o wo o loo Paa ee bee leh ko ka? Tí kò bá jẹ́ bẹ̀, àwọn akitiyan jàndùkú wo ni ọwọ́ ọlọ́ọ̀pá ìbílẹ̀ kò ká?
Play Button What prevents local law enforcement from controlling the local criminal threat? Play Button kee nee ko jeh kee o wo awoH o loo Paa ee bee leh ka eh woo a kee tee yaH jaan do koo? Kíni kò jẹ́ kí ọwọ́ àwọn ọlọ́ọ̀pá ìbílẹ̀ ká ewu akitiyan jàndùkú?
Play Button What specific criminal threats pose the greatest concern for US Forces in the area? Play Button kee nee a kee tee yaH jaan do koo ko tee o jeh ohn kaa yee fee ohn laa fU awoH o mo o gU aamee ree ka nee aBeBe no? Kíni akitiyan jàndùkú kan tí ó jẹ́ ohun kàyéfì nlá fún àwọn ọmọ ogun Amẹ́ríkà ní agbègbè ná à?
Go To Main Menu Print Page DLIFLC 2007 PagePage Total next page