|
Are there problems with ammunition for the weapons? |
|
|
shay ee da moo wa neePa o ta fU awoH oo hu ee ja? |
|
Ṣé ìdàmú wà nípa ọta fún áwọn ohun ìjà? |
|
|
Who buys the ammunition? |
|
|
taa nee on raa awoH o ta naa? |
|
Tani ó n ra áwọn ọta ná à? |
|
|
Where is the ammunition stored? |
|
|
ee bo nee woH on ta jo awoH o ta see? |
|
Ibo ni nwọ́n n tọ́jú áwọn ọta sí? |
|
|
Where is the ammunition bought? |
|
|
ee bo nee woH tee on ra awoH o ta naa? |
|
Ibo ni nwọ́n ti n ra áwọn ọta ná à? |
|
|
How much ammunition is available for each weapon system? |
|
|
o ta may lo nee o wa fU ee to oo hu ee ja ka ka? |
|
Ọta méèló ni ó wà fún ètò ohun ìjà kànkan? |
|