|
What is the condition of the weapon? |
|
|
baa wo nee oo hu ee ja naa shay ree? |
|
Báwo ni ohun ìjà ná à ṣe rí? |
|
|
Why is the weapon in this condition? |
|
|
kee lo day tee oo hu ee ja naa ree ba yee? |
|
Kí ló dé tí ohun ìjà ná à rí báàyí? |
|
|
Who maintains the weapons? |
|
|
taa nee on shay ee to jo awoH oo hu ee ja naa? |
|
Tani ó n ṣe ìtọ́jú áwọn ohun ìjà ná à? |
|
|
How do you get replacement parts and weapons? |
|
|
baa wo nee a shay on ree Paatee a tee oo hu ee ja tUtU? |
|
Báwo ni ẹ ṣe n rí páàtì àti ohun ìjà túntún? |
|
|
Where are the weapons stored? |
|
|
ee bo nee woH on to jo awoH oo hu ee ja see? |
|
Ibo ni nwọ́n n tọ́jú áwọn ohun ìjà sí? |
|