|
Where and when did you observe the improvised explosive device (IED)? |
|
|
ee Ba wo a tee ee bo nee o tee ree bomb Pa ja wee ree naa? |
|
Ìgbàwo àti ibo ni o ti rí bọ́mùbù pàjáwìrì(IED)ná à? |
|
|
Who emplaced the improvised explosive device (IED)? |
|
|
taa nee o keh bomb Pa ja wee ree naa see leh? |
|
Tani ó kẹ́ bọ́mùbù pàjáwìrì(IED)ná à sílè? |
|
|
How is the improvised explosive device (IED) detonated? |
|
|
baa wo nee woH shay in yE bomb boo Pa ja wee ree naa? |
|
Báwo ni nwọ́n ṣe n yin bọ́mùbù pàjáwìrì (IED)ná à? |
|
|
What types of ammunition are used in the explosive device? |
|
|
awoH ee roo o ta wo nee woH in lo fU bomb boo Pa ja wee ree naa? |
|
Àwọn irú ọta wo ni nwọ́n nlo fún bọ́mùbù pàjáwìrì (IED)ná à? |
|
|
Is this improvised explosive device (IED) located in a vehicle? |
|
|
shay bomb boo Pa ja wee ree wa nee no o ko kaH? |
|
Ṣé bọ́mùbù pàjáwìrì (IED)wà nínú ọkọ̀ kan? |
|
|
Where is the owner of this vehicle? |
|
|
ee bo nee a nee tee o nee o ko naa wa? |
|
Ibo ni ẹni tí ó ni ọkọ̀ ná à wà? |
|
|
Who made the improvised explosive device (IED)? |
|
|
taa nee o shay bomb boo Pa ja wee ree naa? |
|
Tani ó ṣe bọ́mùbù pàjáwìrì (IED)ná à? |
|
|
Where was the improvised explosive device (IED) built? |
|
|
ee bo nee woH tee shay bomb boo Pa ja wee ree naa? |
|
Ibo ni nwọ́n ti ṣe bọ́mùbù pàjáwìrì (IED)ná à? |
|
|
Where was the improvised explosive device (IED) stored prior to emplacement? |
|
|
ee bo nee woH to jo bomb boo Pa ja wee ree naa see kee woH to keh see leh? |
|
Ibo ni nwọ́n tọ́jú bọ́mùbù pàjáwìrì (IED)ná à sí kí nwọ́n tó kẹ sílẹ̀? |
|
|
Is there a second or backup detonator? |
|
|
shay a nee kay jee wa laa tee yE? |
|
Ṣé ẹnìkejì wà láti yì í n? |
|
|
Is there a secondary device to attack aid and rescue workers? |
|
|
shay in ka ee woo ee kay jee wa laatee shay ee jaam ba fU awoH aBa nee lah? |
|
Ṣé nkan ewu èkejì wà láti ṣe ìjàmbá fún àwọn agbanilà? |
|
|
Who is the target of this improvised explosive device (IED)? |
|
|
taa nee woH feh shay ee jaam ba fU Pey loo bomb boo Pa ja wee ree yee? |
|
Tani nwọ́n fẹ́ ṣe ìjàmbá fún pẹ̀lú bọ́mùbù pàjáwìrì (IED)yì í? |
|
|
What else can you tell me about the improvised explosive device (IED) or the individuals involved? |
|
|
in ka wo nee o to lay so fU mee nee Pa bomb boo Pa ja wee ree yee taa bee awoH tee o wa nee dee reh? |
|
Nkan wo ni o tú lè sọ fún mi nípa bọ́mùbù pàjáwìrì (IED)yì í tàbí àwọn tí ó wà ní 'dí rẹ̀? |
|