|
What is the type and name of the boat? |
|
|
ee roo o ko o jo o mee wo nee a tee kee nee o roo ko ray? |
|
Irú ọkọ̀ ojú omi wo ni àti kíni orúkọ́ rẹ̀? |
|
|
What weapons are mounted on the boat? |
|
|
ee roo awoH oo hu ee ja wo nee woH Beh see o ree o ko o jo o mee naa? |
|
Irú àwọn ohun ìjà wo ni nwọ́n gbé sí orí ọkọ̀ ojú omi ná à? |
|
|
Does a military or a civilian manufacturer produce the boat? |
|
|
shay awoH o lo gU taa bee o shay loo in shay o ko o jo o mee yee? |
|
Ṣé àwọn ológun tàbí òṣèlú n ṣe ọkọ̀ ojú omi yì í? |
|
|
Does this boat belong to the military? |
|
|
shay awoH o lo gU lo nee o ko o jo o mee yee? |
|
Ṣé àwọn ológun ló ni ọkọ̀ ojú omi yì í? |
|
|
What identifying marks are located on the boat? Weapons? Equipment? |
|
|
awoH a mee wo nee o wa laara oko o jo o mee? oo hu ee ja? ee roo? |
|
Àwọn àmì wo ni ó wà lára ọkọ̀ ojú omi? Ohun ìjà? Ẹrọ? |
|
|
Is there a communication mast on the boat? |
|
|
shay o Po ray dee yo ee baa nee so roo wa looree o ko o jo o mee naa? |
|
Ṣé òpó rédíò ìbáni ṣọ̀rọ̀ wà lórí ọkọ̀ ojú omi ná à? |
|
|
Where and when did you last observe this boat? |
|
|
ee Ba wo a tee ee bo nee o tee ree o ko o jo o mee yee Ba yE? |
|
Ìgbàwo àti ibo ni o ti rí ọkọ̀ ojú omi yì í gbẹ̀yìn? |
|
|
Did another boat support and protect this boat? |
|
|
shay o ko o jo o mee meeraH tel lay o ko yee laa tee shay ee da bo bo fU? |
|
Ṣé ọkọ̀ ojú omi míràn tẹ̀lé ọkọ̀ yì láti ṣe ìdábòbò fun? |
|
|
Did the boat have a flat or round bottom? |
|
|
shay o ko o jo o mee naa nee ee sa lay Pa tey leh taa bee ee sa lay roo bo to? |
|
Ṣé ọkọ̀ ojú omi ná à ní ìsàlẹ̀ pẹ̀tẹ́lẹ̀ tàbí ìsàlẹ̀ roboto? |
|
|
Where is the vehicle stored? |
|
|
ee bo nee in woH in ta jo o ko naa see? |
|
Ibo ni nwọ́n n tọ́jú ọkọ̀ ná à sí? |
|