 |
What is the type and name of the vehicle? |
 |
 |
ee roo o ko wo nee a tee kee nee o roo ko ray? |
 |
Irú ọkọ̀ wo ni àti kíni orúkọ́ rẹ̀? |
 |
 |
What types of weapons were mounted on the vehicle? |
 |
 |
ee roo awoH oo hu ee ja wo nee woH Beh see o ree o ko naa? |
 |
Irú àwọn ohun ìjà wo ni nwọ́n gbé sí orí ọkọ̀ ná à? |
 |
 |
Where and when did you last observe this vehicle? |
 |
 |
ee Ba wo a tee ee bo nee o tee ree o ko yee Ba yE? |
 |
Ìgbàwo àti ibo ni o ti rí ọkọ̀ yì í gbẹ̀yìn? |
 |
 |
Where is the vehicle stored? |
 |
 |
ee bo nee woH in ta jo o ko naa see? |
 |
Ibo ni nwọ́n n tọ́jú ọkọ̀ ná à sí? |
 |
 |
Is this vehicle military or civilian? |
 |
 |
shay o ko awoH o lo gU taa bee o shay loo nee yee? |
 |
Ṣé ọkọ̀ àwọn ológun tàbí òṣèlú nì yí? |
 |
 |
What changes have been made to the vehicle? |
 |
 |
kee nee woH tee shay see o ko naa? |
 |
Kíni nwọ́n ti ṣe sí ọkọ̀ ná à? |
 |
 |
Is the vehicle wheeled or tracked? |
 |
 |
shay o ko o nee ta ya nee taa bee o nee taa ya o jo ee rE nee? |
 |
Ṣé ọkọ̀ o ní táyà ni tàbí o ní táyà ojú irin ni? |
 |
 |
Does the vehicle have a communications system? |
 |
 |
shay o ko naa nee ray dee yo ee ba nee so roo? |
 |
Ṣé ọkọ̀ ná à ní rédíò ìbáni ṣọ̀rọ̀? |
 |
 |
Describe the vehicle to me. |
 |
 |
shay a Pay jo weh o ko naa fU mee |
 |
Ṣé àpèjúwe ọkọ̀ ná à fún mi |
 |
 |
What else can you tell me about this vehicle? |
 |
 |
in ka wo nee o to lay so fU mee nee Pa o ko yee? |
 |
Nkan wo ni o tú lè sọ fún mi nípa ọkọ̀ yì í? |
 |