|
What is the caliber and type of the weapon? |
|
|
kee nee fee feh o ta aa tee ee roo oo hu ee ja naa? |
|
Kíni fífẹ̀ ọta àti irú ohun ìjà ná à? |
|
|
Is this a direct fire weapon like a rifle or bazooka? |
|
|
shay oo hu ee ja ohn laa bee eeboH sa ka boo laa taa bee baa soo ka nee? |
|
Ṣé ohun ìjà nlá bí i ìbọn ṣakabùlà tàbí bàsúkà ni? |
|
|
Is this an indirect fire weapon like a mortar or cannon? |
|
|
shay oo hu ee ja ee roo a yE boH ohn laa nee? |
|
Ṣé ohun ìjà èrọ ayìbọn nlá ni? |
|
|
Was the weapon mounted on a tripod? |
|
|
shay woH Beh ohn ee ja naa lay aa ga ray nee? |
|
Ṣé nwọ́n gbé ohun ìjà ná à lé agéré ni? |
|
|
How many personnel operated this specific weapon? |
|
|
awoH o see sheh may lo nee o lo ohn ee ja yee? |
|
Àwọn òṣìṣẹ́ méèló ni ó lo ohun ìjà yì í? |
|
|
Where and when did you see this weapon? |
|
|
ee Ba wo aa tee ee bo nee o tee ree oo hu ee ja yee? |
|
Ìgbàwo àti ibo ni o ti rí ohun ìjà yì í? |
|
|
What was the approximate size of the projectile? |
|
|
baa wo nee o ta naa shay to bee to? |
|
Báwo ni ota ná à ṣe tóbi tó? |
|
|
Has the weapon been modified in any way? |
|
|
shay woH tee tU oo hu ee ja naa to? |
|
Ṣé nwọ́n ti tún ohun ìjà ná à tò? |
|
|
How effective was the crew operating the weapon? (accuracy in training) |
|
|
baa wo nee awoH o see sheh tee ohn lo oo hu ee ja yee shay feh jo to? (eeko a feh jo) |
|
Báwo ni àwọn òṣìṣẹ́ tí ó nlo ohun ìjà yì í ṣe fínjú tó?(ẹ̀kọ́ afínjú) |
|
|
Was the crew accurate? |
|
|
shay awoH o see sheh naa feh jo? |
|
Ṣé àwọn òṣìṣẹ́ ná à fínjú? |
|
|
How was the crew trained? |
|
|
baa wo nee awoH o see sheh naa shay Bayko? |
|
Báwo ni àwọn òṣìṣẹ́ ná à ṣe gbẹ̀kọ́? |
|
|
What identifying marks were on the weapon? |
|
|
awoH aa mee wo nee o wa laara oo hu ee ja naa? |
|
Àwọn àmì wo ni ó wà lára ohun ìjà ná à? |
|
|
How fast did this weapon fire? How many rounds (bullets) per minute? |
|
|
baa wo nee oo hu ee ja yee shay yaara to? o ta may lo lo ja day laarE ee seh jo ka? |
|
Báwo ni ohun ìjà yì í ṣe yára tó? Ota méèló ló jáde láàrín ìṣẹ́jú kan? |
|
|
Did the crew perform barrel changes? |
|
|
shay awoH o see sheh naa Paa roo aBa eeboH? |
|
Ṣé àwọn òṣìṣẹ́ ná à pàrọ̀ àgbá ìbọn? |
|
|
Did the gun crew have a radio or binoculars? |
|
|
shay awoH o see sheh naa nee ray dee yo ee baa nee so roo taa bee oo hu ee wo o ray ray? |
|
Ṣé àwọn òṣìṣẹ́ ná à ní rédíò ìbáni sọ̀rọ̀ tàbí ohun ìwò òréré? |
|