|
What is the caliber and type of the weapon? |
|
|
kee nee fee feh o ta a tee ee roo oo hu ee ja naa? |
|
Kíni fífẹ̀ ọta àti irú ohun ìjà ná à? |
|
|
How large was the rifle? |
|
|
baa wo nee eeboH naa shay to? |
|
Báwo ni ìbọn ná à ṣe tó? |
|
|
Did the rifle have a scope? |
|
|
shay eeboH naa nee ta jey tee looree? |
|
Ṣé ìbọn ná à ní tájẹ́tì lórí? |
|
|
Was any part of the weapon made of wood? |
|
|
shay oo hu ee ja naa nee ee gee laara? |
|
Ṣé ohun ìjà ná à ní igi lára? |
|
|
Could the part of the rifle, which touches the shoulder, be folded? |
|
|
shay eeka eeboH naa shay ka ko? |
|
Ṣé èèkàn ìbọn ná à ṣe ká kò? |
|
|
How large was the magazine? |
|
|
baa wo nee ee lay o ta naa shay to? |
|
Báwo ni ilé ọta ná à ṣe tó? |
|
|
Was other equipment added to the weapon? |
|
|
shay in ka meeraH pey loo oo hu ee ja naa? |
|
Ṣé nkan míràn pẹ̀lú ohun ìjà ná à? |
|
|
What other equipment was near the weapon? |
|
|
kee nee in ka meeraH tee o sU ma oo hu ee ja naa? |
|
Kíni nkan míràn tí ó sún mọ́ ohun ìjà ná à? |
|
|
What was the size of the pistol? |
|
|
baa wo nee eeboH pee see to naa shay to? |
|
Báwo ni ìbọn písítù ná à ṣe tó? |
|
|
Where was the pistol carried? |
|
|
ee bo nee eeboH pee see to naa wa? |
|
Ibo ni ìbọn písítù ná à wà? |
|