 |
We are establishing a defile (a narrow passage that constricts the movement of troops and vehicles). |
 |
 |
a feh shay ee da no roo (eh yee jeh o no tee rE tee o maa ohn daa ee laa awoH o mo o gU a tee oo ko woH roo) |
 |
A fẹ́ ṣe ìdànọ̀ rú (èyí jẹ́ ọ̀nà tínrín, tí ó ma n da ìlà àwọn ọmọ ogun àti ọkọ̀ nwọn rú ) |
 |
 |
The MP will allow traffic to move in only one direction at a time through the defile. |
 |
 |
awoH sho jaa o loo Pa maa Pa sheh kee BoBo oo ko ko ree see o jo o no ko laa rE ee daa no roo yee |
 |
Àwọn MP ma pàṣẹ kí gbogbo ọkọ̀ kọrí sí ojú ọ̀nà kan làárin ìdànọ̀ rú yì í |
 |
 |
Controls at defiles ensure that traffic moves with little delay. |
 |
 |
nee to ree awoH ee laa no ko nee see ee daa doo roo fU awoH oo ko laa rE ee daa no roo |
 |
Nítorí àwọn ìlànà, kò ní sí ìdádúró fún àwọn ọkọ̀ làárin ìdànọ̀ rú |
 |
 |
Have you been checked by security? |
 |
 |
shay woH tee shay a Beh wo reh? |
 |
Ṣé nwọ́n tí ṣe àbẹ̀wò rẹ́? |
 |
 |
Is there heavy traffic in this area? |
 |
 |
shay go see loo Po nee aBeBe yee? |
 |
Ṣé gósilò pọ̀ ní agbègbè yì í? |
 |
 |
Do you know that this road is off limits to local residents? |
 |
 |
shay o mo wee Pay awoH aa raa ee loo ko lay Ba tee tee yee? |
 |
Ṣé o mọ̀ wìpé àwọn ará ìlú kò lè gba títì yì í? |
 |
 |
Move in one direction only. |
 |
 |
eh ko ree see o jo o no ko |
 |
Ẹ kọrí sí ojú ọ̀nà kan |
 |
 |
Proceed after military vehicles have passed. |
 |
 |
tee oo ko awoH o loo gU baa tee ko jaa nee kee oo ko jaa |
 |
Tí ọkọ̀ àwọn ológun bá ti kọjá ni kí o kọjá |
 |
 |
Do not bypass the security checkpoint. |
 |
 |
maa Ba eh Beh sheh kee po yin tee ko jaa |
 |
Má gba ẹ̀gbẹ́ ṣẹ́kí pọnìtì kọjá |
 |
 |
Please follow the signs. |
 |
 |
jo wo tel lay awoH aa mee |
 |
Jọ̀wọ́ tẹ̀lẹ́ àwọn àmì |
 |