 |
We are leading a convoy through this area. |
 |
 |
a feh moo awoH oo ko ee rE aa jo ko jaa ee bee yee |
 |
A fẹ́ mú àwọn ọkọ̀ ìrìnàjò kọjá ibí yì í |
 |
 |
We are responsible for the security of the convoy. |
 |
 |
ee sheh waa nee ee da bo bo fU awoH oo ko ee rE aa jo na |
 |
Iṣẹ́ wa ni ìdábòbò fún àwọn ọkọ̀ ìrìnàjò ná à |
 |
 |
We must conduct safety inspections on all the vehicles. |
 |
 |
a nee laa tee shay a bay wo BoBo awoH oo ko |
 |
A ní láti ṣe àbẹ̀wọ̀ gbogbo àwọn ọkọ̀ |
 |
 |
We must drive the convoy through this intersection. |
 |
 |
a nee laa tee waa awoH oo ko ee rE aa jo ko jaa nee jo kee sho no yee |
 |
A ní láti wa àwọn ọkọ̀ ìrìnàjò kọjá ní jọ́nkíṣọ̀nù yì í |
 |
 |
We are escorting the convoy. |
 |
 |
a ohn moo awoH oo ko ee rE aa jo yee ko jaa |
 |
A n mú àwọn ọkọ̀ ìrìnàjò yì í kọjá |
 |
 |
We must seek an alternate route. |
 |
 |
a nee laa tee waa o no meeraH |
 |
A ní láti wa ọ̀nà míràn |
 |
 |
We will use tanks to detonate mines. |
 |
 |
a maa loo oo ko o gU ohn laa laa tee ya jo o hU ee jaa o loo roo ee no ee leh |
 |
A ma lo ọkọ̀ ogun nlá láti yanjú oun ìjà olóró inú ilẹ̀ |
 |
 |
Snipers may fire on convoys in this area. |
 |
 |
awoH a fE jo o nee boH leh nee bo fU awoH oo ko ee rE aa jo nee aBeBe yee |
 |
Àwọn afínjú oníbọn lè yìnbọn fún àwọn ọkọ̀ ìrìnàjò ní agbègbè yì í |
 |
 |
Unexploded ordnance may be planted in the road. |
 |
 |
woH lay ree o hU ee jaam baa o loo roo see no ee leh |
 |
Nwọ́n lè ri oun ìjàmbá olóró sínú ilẹ̀ |
 |
 |
The convoy will continue when the ambush is suppressed. |
 |
 |
awoH oo ko ee rE aa jo yee a maa ko jaa loo tee woh baa tee ya jo awoH o loo day no |
 |
Àwọn ọkọ̀ ìrìnàjò yì í á ma kọjá lọ tí nwọ́n bá ti yanjú àwọn olùdènà |
 |
 |
Is there a bridge to cross the river? |
 |
 |
shay a faa raa waa laa tee ko jaa o do na? |
 |
Ṣẹ́ afárá wà láti kọjá odò ná à? |
 |
 |
Will this bridge support heavy vehicles? |
 |
 |
shay a faa raa yee lay Beh awoH oo ko ohn laa? |
 |
Ṣẹ́ afárá yì í lè gbé àwọn ọkọ̀ nlá? |
 |
 |
Does this road lead through any towns? |
 |
 |
shay o no yee Ba aa rE ee loo ko jaa? |
 |
Ṣẹ́ ọ̀nà yì í gba àárín ìlú kọjá? |
 |
 |
Does this road lead through heavy traffic areas? |
 |
 |
shay o no yee Ba aa rE ee bee go see loo ko jaa? |
 |
Ṣẹ́ ọ̀nà yì í gba àárín ibi gósilò kọjá? |
 |
 |
Are there friendly units in this area? |
 |
 |
shay awoH eh Beh o loo gU aa raa wa waa nee aBeBe yee? |
 |
Ṣé àwọn ẹgbẹ́ ológun arawa wà ní agbègbè yì í? |
 |
 |
Was enemy activity reported in this area? |
 |
 |
shay woH so nee Pa aa kee tee ya awoH eh Beh o loo gU o taa nee aBeBe yee? |
 |
Ṣé nwọ́n sọ nípa akitiyan àwọn ẹgbẹ́ ológun ọ̀tá ní agbègbè yì í? |
 |
 |
Are there checkpoints on this road? |
 |
 |
shay awoH sheh kee po yin tee waa nee o no yee? |
 |
Ṣé àwọn ṣẹ́kí pọnìtì wà ní ọ̀nà yì í? |
 |
 |
Is there a site to refuel? |
 |
 |
shay ee bee tee woH tee ohn roo Po waa? |
 |
Ṣé ibi tí nwọ́n ti rọ'po wà? |
 |
 |
Are there areas to take cover? |
 |
 |
shay ee bee a bo waa nee Ba Pa jaa wee ree eh woo? |
 |
Ṣé ibi àbò wà nígbà pàjáwìrì ewu? |
 |
 |
We need assistance. |
 |
 |
a feh ee raH loo wo |
 |
A fẹ́ ìrànlọ́wọ́ |
 |
 |
Look out for booby traps in the area. |
 |
 |
sho ra fU ee woo ee taH jeh awoH o taa nee aBeBe yee |
 |
Ṣọ́ra fún ewu ìtànjẹ àwọn ọ̀tá ní agbègbè yì í |
 |
 |
Do not drive on the shoulder of the road. |
 |
 |
maa shay waa oo ko nee eh baa tee tee |
 |
Má ṣe wa ọkọ̀ ní ẹ̀bá títì |
 |
 |
Follow the vehicle in front of you. |
 |
 |
tel lay oo ko tee o waa nee ee waa jo reh |
 |
Tẹ̀lẹ́ ọkọ̀ tí ó wà ní iwájú rẹ |
 |