 |
We will process enemy prisoners of war (EPWs). |
 |
 |
a maa tee awoH eh Beh o gU o taa mo lay |
 |
A ma ti àwọn ẹgbẹ́ ogun ọ̀tá (EPW) mọ́'lé |
 |
 |
MPs will repatriate EPWs and CIs (civilians internees) later. |
 |
 |
awoH sho jaa o loo Pa maa da awoH eh Beh o gU o taa aa tee (awoH aa raa ee loo tee aa moo) Pa daa see loo |
 |
Àwọn MP má a dá àwọn EPW àti CI (àwọn ará ìlú tí a mú) padà sí'lú |
 |
 |
We will handle all EPWs and CIs according to the provisions of the Geneva Convention. |
 |
 |
a maa shay to awoH eh Beh o gU o taa a tee awoH aa raa ee loo tee aa moo geh geh bee o fE gee nee faa |
 |
A ma ṣè'tò àwọn EPW àti àwọn CI gẹ́gẹ́ bí òfin jẹ̀nẹ́fà |
 |
 |
First aid will be provided for all wounded. |
 |
 |
woH maa Pay say ee raH loo wo fU awoH tee o shay shay |
 |
Nwọ́n ma pèsè ìrànlọ́wọ́ fún àwọn tí ó ṣèṣe |
 |
 |
We will protect all EPWs and CIs against ill treatment. |
 |
 |
a maa shay ee da bo bo fU BoBo awoH eh Beh o gU o taa a tee awoH aa raa ee loo tee aa moo |
 |
A ma ṣe ìdábòbò fún gbogbo àwọn EPW àti àwọn CI |
 |
 |
All EPWs and CIs will be searched and tagged. |
 |
 |
a maa shay a Beh wo BoBo awoH eh Beh o gU o taa a tee awoH aa raa ee loo tee aa moo |
 |
A ma ṣe àbẹ̀wọ̀ gbogbo àwọn EPW àti àwọn CI |
 |
 |
We will safeguard your money and valuables. |
 |
 |
a maa shay ee da bo bo fU o wo a tee awoH ohn ee nee reh |
 |
A ma ṣe ìdábòbò fún owó àti àwọn oun ìní rẹ |
 |
 |
We will give you a receipt for your money and valuables. |
 |
 |
a maa fU eh nee ee way eh ree fU o wo aa tee awoH ohn ee nee reh |
 |
A ma fún ẹ ní ìwé ẹ̀rí fún owó àti àwọn oun ìní rẹ |
 |
 |
Money and valuables will be returned to you. |
 |
 |
woH maa daa o wo a tee awoH ohn ee nee reh Pa daa fU eh |
 |
Nwọ́n ma dá owó àti àwọn oun ìní rẹ padà fún ẹ |
 |
 |
We will lead you to an enclosed area. |
 |
 |
a maa to eh see ee bee tee o nee aa boo |
 |
A ma tọ ẹ sí ibi tí ó ní àbò |
 |
 |
You are allowed to dig foxholes. |
 |
 |
o lay waa ko to fU ee jaa o gU |
 |
O lè wa kòtò fún ìjà ogun |
 |
 |
You are allowed to dig holes in the ground to help shelter you. |
 |
 |
o lay waa ko to fU ee daa bo bo eh |
 |
O lè wa kòtò fún ìdábòbò ẹ |
 |
 |
We have to question you. |
 |
 |
a nee laa tee fo roo waa eh leh no wo |
 |
A ní láti f'ọ̀ro wá ẹ lẹ́nu wò |
 |
 |
Somebody will question you now. |
 |
 |
eh nee ko aa fo roo waa eh leh no wo nee sE sE yee |
 |
Ẹnìkan à f'ọ̀ro wá ẹ lẹ́nu wò nísisìnyí |
 |
 |
You will be taken to another location. |
 |
 |
a maa moo eh loo see ee bo meeraH |
 |
A ma mú ẹ lọ sí ibòmíràn |
 |
 |
You will be assigned an identification number (internment serial number). |
 |
 |
woH maa fU eh nee nom baa ee daa nee mo (nom baa awoH tee a moo nee Ba o gU) |
 |
Nwọ́n ma fún ẹ ní nọ̀mbà ìdánimọ̀ (nọ̀mbà àwọn tí a mú nígbà ogun) |
 |
 |
Your information will be provided to a Prisoner of War Information Center. |
 |
 |
a maa so fU awoH a sho jo awoH eh leh woH tee a moo nee Ba o gU nee Pa eh |
 |
A ma sọ fún àwọn Aṣojú Àwọn Ẹlẹ́wọ̀n tí a mú nígbà Ogun nípa ẹ |
 |
 |
Do you need first aid? |
 |
 |
shay o feh ee raH loo wo ee wo saH nee kee ya kee ya? |
 |
Ṣẹ́ o fẹ́ ìrànlọ́wọ́ ìwòsàn ní kíákíá? |
 |
 |
Are you hurt? |
 |
 |
shay o shay shay? |
 |
Ṣẹ́ o ṣèṣe? |
 |
 |
Do you need food? |
 |
 |
shay o feh ohn jeh? |
 |
Ṣẹ́ o fẹ́ oúnjẹ? |
 |
 |
What is your unit? |
 |
 |
eh Beh o gU wo nee tee eh? |
 |
Ẹgbẹ́ ogun wo ni tì ẹ? |
 |
 |
Do you have any information for us? |
 |
 |
shay o nee ee kay day fU waa? |
 |
Ṣẹ́ o ní ìkéde fún wa? |
 |
 |
Where is your unit? |
 |
 |
ee bo nee awoH eh Beh o gU reh waa? |
 |
Ibo ni àwọn ẹgbẹ́ ogun rẹ wà? |
 |
 |
Provide shelter to protect EPWs from the elements. |
 |
 |
fU awoH eh Beh o gU o taa nee ee lay fU ee da bo bo loo wo awoH eh nee ee bee |
 |
Fún àwọn EPW ní ilé fún ìdábòbò lọ́wọ́ àwọn ẹni ibi |
 |
 |
All male EPWs will be moved to another location. |
 |
 |
a maa ko BoBo awoH eh Ba o mo o gU o taa o kU rE loo see ee bo meeraH |
 |
A ma kó gbogbo àwọn EPW ọkùnrin lọ sí ibòmíràn |
 |