 |
We must identify places where we can receive emergency help. |
 |
 |
a nee laa tee mo awoH ee bee tee a lay tee ree ee raH loo wo Pa jaa wee ree |
 |
A ní láti mọ àwọn ibì tí a lè ti rí ìrànlọ́wọ́ pàjáwìrì |
 |
 |
Our task is to control route security measures. |
 |
 |
ee sheh waa nee laa tee bo jo to eh woo awoH o no ee rE aa jo |
 |
Iṣẹ́ wa ni láti bójútó ewu àwọn ọ̀nà ìrìnàjò |
 |
 |
We'll classify bridges according to weight limits. |
 |
 |
a maa Pi awoH a faa raa nee Pa ee woH oo ko tee woH lay Bay |
 |
A ma pín àwọn afárá nípa ìwọ̀n ọkọ̀ tí nwọn lè gbé |
 |
 |
We need areas suitable for short halts. |
 |
 |
a nee laa tee fee awoH ee bee ko see leh fU ee daa ko doo roo kay kay ray |
 |
A ní láti fi àwọn ibì kan sí'lẹ̀ fún ìdákọ́dúró kékeré |
 |
 |
Where does this road lead to? |
 |
 |
ee bo nee o no yee jaa see? |
 |
Ibo ni ọ̀nà yí já sí? |
 |
 |
Which towns does this road run through? |
 |
 |
awoH ee loo ee bo nee o no yee Baa ko jaa? |
 |
Àwọn ìlú ibo ni ọ̀nà yí gbà kọjá? |
 |
 |
Is the road paved or unpaved? |
 |
 |
shay tee tee o loo daa nee eh yee taa bee eh lay roo koo? |
 |
Ṣé títì ọlọ́dà ni èyí tàbí eléruku? |
 |
 |
Is there an alternate route? |
 |
 |
shay o no meeraH waa? |
 |
Ṣé ọ̀nà míràn wá à? |
 |
 |
Is there a way to bypass this obstacle? |
 |
 |
shay o no waa laa tee ko jaa laa raa ee day no yee? |
 |
Ṣé ọ̀nà wà láti kọjá lára ìdènà yì í? |
 |
 |
Are there bridges on this route? |
 |
 |
shay awoH a faa raa waa nee o no yee? |
 |
Ṣé àwọn afárá wà ní ọ̀nà yì í? |
 |
 |
Are there overpasses on this route? |
 |
 |
shay awoH a faa raa o kay waa nee o no yee? |
 |
Ṣé àwọn afárá òkè wà ní ọ̀nà yì í? |
 |
 |
Is there construction on this route? |
 |
 |
shay woH tU tee tee shay nee o no yee? |
 |
Ṣé nwọ́n n tún títì ṣe ní ọ̀nà yì í? |
 |
 |
Are there many potholes in this road? |
 |
 |
shay ko to Po nee o no yee? |
 |
Ṣé kòtò pọ̀ ní ọ̀nà yì í? |
 |
 |
How wide is the road? |
 |
 |
baa wo nee tee tee na tee feh to? |
 |
Báwo ni títì ná à ti fẹ̀ tó? |
 |
 |
Are there steep hills on this road? |
 |
 |
shay awoH o kay Po nee o no yee? |
 |
Ṣé àwọn òkè pọ̀ ní ọ̀nà yì í? |
 |
 |
Are there sharp curves on this road? |
 |
 |
shay awoH ko na Po nee o no yee? |
 |
Ṣé àwọn kọ́nà pọ̀ ní ọ̀nà yì í? |
 |
 |
Does this route lead through tunnels? |
 |
 |
shay o no yee Ba ee no ee ho ko jaa? |
 |
Ṣé ọ̀nà yì í gba inú ihò kọjá? |
 |
 |
Do you know how to read a map? |
 |
 |
shay o mo maa poo loo? |
 |
Ṣé o mọ máàpù ló ò? |
 |
 |
Are there enemy units in this area? |
 |
 |
shay awoH eh Beh o loo gU o taa waa nee aBeBe yee? |
 |
Ṣé àwọn ẹgbẹ́ ológun ọ̀tá wà ní agbègbè yì í? |
 |
 |
Are there friendly units in this area? |
 |
 |
shay awoH eh Beh o loo gU aa raa wa waa nee aBeBe yee? |
 |
Ṣé àwọn ẹgbẹ́ ológun arawa wà ní agbègbè yì í? |
 |
 |
Are there wooded areas nearby? |
 |
 |
shay awoH ee Bo waa nee aBeBe yee? |
 |
Ṣé àwọn igbó wà ní agbègbè yì í? |
 |
 |
Are there rivers near this route? |
 |
 |
shay awoH o mee o do waa nee aBeBe yee? |
 |
Ṣé àwọn omi odò wà ní agbègbè yì í? |
 |
 |
How many miles? |
 |
 |
maa yee lee may loo? |
 |
Máìlì méèló? |
 |
 |
How many kilometers? |
 |
 |
kee loo mee taa may loo? |
 |
Kìlómítà méèló? |
 |
 |
Are there major highways on this route? |
 |
 |
shay awoH tee tee ee rE aa jo ohn laa waa nee o no yee? |
 |
Ṣé àwọn títì ìrìnàjò nlá wà ní ọ̀nà yì í? |
 |
 |
Are any major roads on this route? |
 |
 |
shay awoH tee tee ohn laa waa nee o no yee? |
 |
Ṣé àwọn títì nlá wà ní ọ̀nà yì í? |
 |
 |
Is there a railway near this road? |
 |
 |
shay ray loo way waa nee eh baa o no yee? |
 |
Ṣé rélùweè wà ní ẹ̀bá ọ̀nà yì í? |
 |
 |
Are the railway tracks in use? |
 |
 |
shay o no ray loo way na ohn shee sheh? |
 |
Ṣé ọ̀nà rélùweè ná à nṣiṣẹ́? |
 |
 |
Is there a railway crossing? |
 |
 |
shay ee soo daa o no ray loo way waa? |
 |
Ṣé ìsọdá ọ̀nà rélùweè wà? |
 |
 |
Are there any busy intersections on this route? |
 |
 |
shay go see loo waa nee bee awoH jon kee sho no o no yee? |
 |
Ṣé gósilò wà níbi àwọn jọ́nkíṣọ̀nù ọ̀nà yì í? |
 |
 |
Does this route experience heavy traffic? |
 |
 |
shay go see loo maa ohn waa nee o no yee? |
 |
Ṣé gósilò má a nwà ní ọ̀nà yì í? |
 |
 |
Does this road have curbs? |
 |
 |
shay tee tee yee nee eh tee eh baa o no? |
 |
Ṣé títì yì í ní etí ẹ̀bá ọ̀nà? |
 |
 |
Are there sidewalks lining the road? |
 |
 |
shay tee tee yee nee eh baa ee rE seh? |
 |
Ṣé títì yì í ní ẹ̀bá ìrìnsẹ̀? |
 |
 |
Is there pedestrian traffic on the road? |
 |
 |
shay awoH eh leh seh tee o ohn soo daa nee tee tee na Po? |
 |
Ṣé àwọn ẹlẹ́sẹ̀ tí ó n'sọdá ní títì ná à pọ̀? |
 |
 |
Are there any minefields near this route? |
 |
 |
shay awoH PaPa tee o nee ohn ee jaa o loo roo ee no ee leh waa nee o no yee? |
 |
Ṣé àwọn pápá tí ó ní oun ìjà olóró inú ilẹ̀ wà ní ọ̀nà yì í? |
 |
 |
Are there any landmarks near this route? |
 |
 |
shay awoH ohn ko Pa taa kee waa nee o no yee? |
 |
Ṣé àwọn nkan pàtàkì wà ní ọ̀nà yì í? |
 |
 |
How much weight can the bridge carry? |
 |
 |
ee woh oo ko may loo nee a faa raa na lay Bay? |
 |
Ìwọ̀n ọkọ̀ méèló ni afárá ná à lè gbé? |
 |
 |
What material is the bridge made of? |
 |
 |
kee nee woH fee ko a faa raa na? |
 |
Kíni nwọ́n fi kọ afárá ná à? |
 |
 |
How wide is the tunnel? |
 |
 |
baa wo nee tee tee ee no ee ho tee feh to? |
 |
Báwo ni títì inú ihò ti fẹ̀ tó? |
 |
 |
How high is the tunnel? |
 |
 |
baa wo nee tee tee ee no ee ho tee ga to? |
 |
Báwo ni títì inú ihò ti ga tó? |
 |
 |
How long is the tunnel? |
 |
 |
baa wo nee tee tee ee no ee ho tee gU to? |
 |
Báwo ni títì inú ihò ti gùn tó? |
 |
 |
Is there a checkpoint on this road? |
 |
 |
shay sheh kee po yin tee waa nee o no yee? |
 |
Ṣé ṣẹ́kí pọnìtì wà ní ọ̀nà yì í? |
 |
 |
Is there a defile (a narrow passage that constricts the movement of troops and vehicles) on this road? |
 |
 |
shay ee da no roo (eh yee jeh o no tee rE tee o maa ohn daa ee laa awoH o mo o gU a tee oo ko woH roo) waa nee o no yee? |
 |
Ṣé ìdànọ̀ rú (èyí jẹ́ ọ̀nà tínrín, tí ó ma n da ìlà àwọn ọmọ ogun àti ọkọ̀ nwọn rú ) wà ní ọ̀nà yì í? |
 |
 |
Is a defile being planned on the road? |
 |
 |
shay eh to ee daa no roo waa fU o no yee? |
 |
Ṣé ètò ìdànọ̀ rú wà fún ọ̀nà yì í? |
 |
 |
Is the road blocked? |
 |
 |
shay o no tee dee? |
 |
Ṣé ọ̀nà ti dí? |
 |
 |
Does the road get narrow? |
 |
 |
shay o no no ohn dee kay kay ray? |
 |
Ṣé ọ̀nà ná à n di kékeré? |
 |
 |
Are there overhead obstructions on this route? |
 |
 |
shay awoH ee dee no o kay waa nee o no yee? |
 |
Ṣé àwọn ìdínà òkè wà ní ọ̀nà yì í? |
 |
 |
What is the lowest overhead clearance on this route? |
 |
 |
ee dee na o kay wo nee o waa see leh jo nee o no yee? |
 |
Ìdínà òkè wo ni ó wà sílẹ̀ jù ní ọ̀nà yì í? |
 |
 |
Can you cross the river at this location? |
 |
 |
shay o lay ko jaa o do nee bee yee? |
 |
Ṣé o lè kọjá odò níbí yì í? |
 |
 |
How wide is the river at this crossing point? |
 |
 |
baa wo nee o do no tee feh to nee ee bee ee soo daa yee? |
 |
Báwo ni odò ná à ti fẹ̀ tó ní ibi ìsọdá yì í? |
 |
 |
Can the crossing be used by vehicles? |
 |
 |
shay awoH oo ko lay loo ee bee ee soo daa yee? |
 |
Ṣé àwọn ọkọ̀ lè lo ibi ìsọdá yì í? |
 |
 |
Is this a fast-moving stream? |
 |
 |
shay o do shee sho nee yee? |
 |
Ṣé odò ṣíṣàn nì yí? |
 |
 |
How fast is the water in this river? |
 |
 |
baa wo nee o do shee sho no tee ohn saa ray see? |
 |
Báwo ni odò ṣíṣàn ná à ti n sáré sí? |
 |
 |
How deep is this waterway? |
 |
 |
baa wo nee o do no tee jin see? |
 |
Báwo ni odò ná à ti jìn sí? |
 |
 |
Can the stream be crossed during this time of year? |
 |
 |
shay woH lay ko jaa o do no nee a ko ko o dU yee? |
 |
Ṣé nwọ́n lè kọjá odò ná à ní àkokò odún yì í? |
 |
 |
Does this river flood suddenly during this time of year? |
 |
 |
shay o mee o do no maa ohn ya nee o jee jee nee a ko ko o dU yee? |
 |
Ṣé omí odò ná à má a n'ya ní òjijì ní àkokò odún yì í? |
 |
 |
Are there a lot of large rocks in the riverbed? |
 |
 |
shay awoH oo ko taa ohn laa waa nee no o do no? |
 |
Ṣé àwọn òkúta nlá wà nínú odò ná à? |
 |
 |
Are the riverbanks very steep? |
 |
 |
shay eh tee o do no jee gaH? |
 |
Ṣé etí odò ná à jìn gan? |
 |
 |
Are there barriers on the riverbank? |
 |
 |
shay o Baa waa nee eh tee o do na? |
 |
Ṣé ogbà wà ní etí odò ná à? |
 |
 |
Has the roadway eroded? |
 |
 |
shay o do tee sho tee tee loo? |
 |
Ṣé odò ti ṣan títì lọ? |
 |
 |
Is there any snow on this route? |
 |
 |
shay o jo yEyE roo see o no yee? |
 |
Ṣé òjò yìnyín rọ̀ sí ọ̀nà yì í? |
 |
 |
Is this route covered with ice? |
 |
 |
shay yEyE tee bo o no yee? |
 |
Ṣé yìnyín ti bo ọ̀nà yì í? |
 |
 |
Clear the road. |
 |
 |
Pa o no mo |
 |
Pa ọ̀nà mọ́ |
 |
 |
Mark critical points on the map. |
 |
 |
saa mee see awoH ee bee tee o shay ko ko nee no maa poo yee |
 |
Sà mi sí àwọn ibi tí ó ṣe kókó nínú máàpù yì í |
 |
 |
Show me on the map. |
 |
 |
to ka see mee nee no maa poo yee |
 |
Tọ́'ka sí mi nínú máàpù yì í |
 |