 |
This RB is to limit access to this road. |
 |
 |
ee Bay gee da no yee nee wee Pay kee a maa jeh kee eh roo Ba o no yee ko jaa |
 |
RB yì í ni wípé kí a ma jẹ́ kí èrò gba ọ̀nà yì í kọjá |
 |
 |
This RB is to close access to this road. |
 |
 |
ee Bay gee da no yee nee wee Pay kee a maa jeh kee eh nee ka nee Ba o no yee ko jaa |
 |
RB yì í ni wípé kí a ma jẹ́ kí ẹnikẹ́ni gba ọ̀nà yì í kọjá |
 |
 |
These RBs and CPs will ensure only authorized use of this main supply route (MSR). |
 |
 |
awoH ee Bay gee da no aa tee sheh kee po yin tee maa ree wee Pay awoH tee o Ba a sheh nee o lay Ba o no ohn laa yee ko jaa |
 |
Àwọn RB àti CP ma ri wípé àwọn tí ó gba àṣẹ ni ó lè gba ọ̀nà nlá (MSR) yì í kọjá |
 |
 |
These RBs and CPs will ensure that convoys move on schedule. |
 |
 |
awoH ee Bay gee da no aa tee sheh kee po yin tee maa ree wee Pay awoH oo ko ee rE aa jo loo laa koko |
 |
Àwọn RB àti CP ma ri wípé àwọn ọkọ̀ ìrìnàjò lọ l'àkokò |
 |
 |
The position of RBs/CPs will change constantly. |
 |
 |
ee Po awoH ee Bay gee da no sheh kee po yin tee maa yaa to day day |
 |
Ipò àwọn RB/CP ma y'àtọ̀ dèdè |
 |
 |
In a single team operation one member will stop and direct traffic. |
 |
 |
nee no a kee tee yaH eh Beh o loo gU o mo o gU ko maa doo roo laa tee daa ree awoH oo ko |
 |
Nínú akitiyan ẹgbẹ́ ológun, ọmọ ogun kan ma dúró láti daarí àwọn ọkò |
 |
 |
We don't allow anyone to pass without a proper ID. |
 |
 |
a kee Ba eh nee ka nee laa yee laa tee ko jaa lay ee nee ee way ee da nee mo to jo jo |
 |
A kì í gba ẹnikẹ́ni l'áyè láti kọjá láìnì ìwé ìdánimọ̀ tó jọ'jú |
 |
 |
What is your cargo? |
 |
 |
awoH eh roo eh daa? |
 |
Àwọn ẹrù ẹ dà? |
 |
 |
Where are your cargo documents? |
 |
 |
awoH ee way eh roo eh daa? |
 |
Àwọn ìwé ẹrù ẹ dà? |
 |
 |
Where does your cargo originate from? |
 |
 |
ee bo nee awoH eh roo eh tee waa? |
 |
Ibo ni àwọn ẹrù ẹ ti wá? |
 |
 |
Where did you pick up your cargo? |
 |
 |
ee bo nee o tee Ba awoH eh roo eh? |
 |
Ibo ni o ti gba àwọn ẹrù ẹ? |
 |
 |
What is your destination? |
 |
 |
ee bo nee ohn loo? |
 |
Ibo ni o n lọ? |
 |
 |
We will prevent actions that would aid the enemy. |
 |
 |
a maa ree wee Pay ko see a kee tee yaH tee o lay raH awoH o taa loo wo |
 |
A ma ri wípé kò sí akitiyan tí ó lè ran àwọn ọ̀tá l'ọ́wọ́ |
 |
 |
We will inspect cargo when instructed to do so. |
 |
 |
a maa shay aa Ba wo awoH eh roo tee woH ba so fU waa |
 |
A ma ṣe àbẹ̀wò àwọn ẹrù tí nwọ́n bá sọ́ fún wa |
 |
 |
We will stop locals from supplying the enemy. |
 |
 |
a maa daa awoH aa raa ee loo doo roo laa tee maa lay raH awoH o taa loo wo |
 |
A ma dá àwọn ará ìlú dúró láti má lè ran àwọn ọ̀tá l'ọ́wọ́ |
 |
 |
We are here to stop black market operations. |
 |
 |
a waa laa tee fee o Pi see o jaa a Beh leh |
 |
A wá láti fi òpin sí ọjà abẹ́lẹ̀ |
 |
 |
We will establish an area for searching vehicles. |
 |
 |
a maa fee ee bee ko see leh fU a Beh wo awoH oo ko |
 |
A ma fi ibì kan sí'lẹ̀ fún àbẹ̀wò àwọn ọkọ̀ |
 |
 |
We have vehicles ready to pursue those avoiding the RBs. |
 |
 |
a nee awoH oo ko nee leh laa tee lay awoH tee ohn saa fU ee Bay gee da no |
 |
A ní àwọn ọkọ̀ ní'lẹ̀ láti lé àwọn tí ó n sá fún RB |
 |
 |
We must prepare defensive positions. |
 |
 |
a nee laa tee fee ee bee ko see leh fU a bo bo |
 |
A ní láti fi ibì kan sí'lẹ̀ fún àbòbò |
 |
 |
We will block roadway shoulders and ditches around RBs. |
 |
 |
a maa dee awoH o no aa tee ko to nee aa yee ka ee Bay gee da no |
 |
A ma dí àwọn ọ̀nà àti kòtò ní àyíká RB |
 |