 |
We will set up traffic control points (TCPs) in the area. |
 |
 |
a maa daa sheh kee po yin tee see leh nee aBeBe yee |
 |
A ma dá ṣẹ́kí pọnìtì (TCP) sílẹ̀ ní agbègbè yì í |
 |
 |
The TCP locations will be decided by the MPs. |
 |
 |
awoH o loo Paa sho jaa nee o maa Paa sheh ee bee tee awoH sheh kee po yin tee yee maa waa |
 |
Àwọn ọlọ́ọ̀pá ṣójà (MP) ni ó ma pàṣẹ ibi tí àwọn ṣẹ́kí pọnìtì (TCP) yì í ma wà |
 |
 |
The TCP personnel will work hard to prevent delays. |
 |
 |
awoH o shee sheh sheh kee po yin tee maa tee raa mo sheh laa tee ree wee Pay ko see ee daa doo roo |
 |
Àwọn òṣìṣẹ́ ṣẹ́kí pọnìtì TCP ma tẹ'ra mọ́'ṣẹ́ láti ri wípé kò sí ìdádúró |
 |
 |
Our TCP team will keep records of passing vehicles and units. |
 |
 |
awoH o shee sheh sheh kee po yin tee waa maa to jo eh ree awoH oo ko |
 |
Àwọn òṣìṣẹ́ ṣẹ́kí pọnìtì TCP wa ma tọ́jú ẹ̀rí àwọn ọkọ̀ |
 |
 |
The TCP will apprehend violators. |
 |
 |
o shee sheh sheh kee po yin tee maa moo awoH aa roo fE |
 |
Òṣìṣẹ́ ṣẹ́kí pọnìtì TCP ma mú àwọn arúfin |
 |
 |
Make sure refugee traffic does not delay military traffic. |
 |
 |
ree wee Pay go see loo awoH to gU shee koo roo nee lay ko daa oo ko awoH o loo gU doo roo |
 |
Ri wípé gósilò àwọn t'ógun ṣí kúrò ní'lé kò dá ọkọ̀ àwọn ológun dúró |
 |
 |
The TCP personnel will reroute traffic as needed. |
 |
 |
awoH o shee sheh sheh kee po yin tee maa da ree awoH oo ko bo baa shay jeh |
 |
Àwọn òṣìṣẹ́ ṣẹ́kí pọnìtì TCP ma darí àwọn ọkọ̀ bó bá ṣe jẹ́ |
 |
 |
Our mission is ongoing until further notice. |
 |
 |
awoH ee daa wo lay waa ohn loo laa ee see ee daa doo roo |
 |
Àwọn ìdáwọ́lé wa n lọ lá ì sí ìdádúró |
 |
 |
Food and water will be supplied by other units. |
 |
 |
awoH eh Beh o loo gU meeraH maa Pay say ohn jeh aa tee o mee |
 |
Àwọn ẹgbẹ́ ológun mìíràn ma pèsè oúnjẹ àti omi |
 |
 |
Nuclear, biological and chemical (NBC) detection equipment will be provided. |
 |
 |
a maa Pay say eh roo tee o maa ree eh roo jaa noo kee laa, baa yoo loo jee kaa lee aa tee kaa mee kaa lee |
 |
A ma pèsè ẹ̀rọ tí ó ma rí éròjà núkílà, bàyọ́lọ́jíkàlì àti kẹ́míkàlì (NBC) |
 |
 |
Reflective arm cuffs will be provided. |
 |
 |
a maa Pay say a moo ko foo to ohn daH |
 |
A ma pèsè ámù kọfù tó n dán |
 |
 |
Enemy may use agents acting as refugees. |
 |
 |
awoH o taa lay dee bo bee awoH to gU shee koo roo nee lay |
 |
Àwọn ọ̀tá lè díbọ́n bí i àwọn t'ógun ṣí kúrò ní'lé |
 |
 |
Safety is very important during all operations. |
 |
 |
ee daa bo bo shay ko ko nee no BoBo a kee tee yaH |
 |
Ìdábòbò ṣe kókó nínú gbogbo akitiyan |
 |
 |
We do not allow unauthorized personnel to observe traffic movement. |
 |
 |
a ko Baa kee o shee sheh tee ko Baa a sheh shay a ko soo ee laa no ee rE aa jo awoH oo ko |
 |
A kò gbà kí òṣìṣẹ́ tí kò gba àṣẹ ṣe àkóso ìlànà ìrìnàjò àwọn ọkọ̀ |
 |
 |
What is the size of the enemy force? |
 |
 |
may loo nee o mo o loo gU awoH o taa? |
 |
Méèló ni ọmọ ológun àwọn ọ̀tá? |
 |
 |
Where is the exact location of the enemy? |
 |
 |
ee bo gaH gaH nee awoH o taa waa? |
 |
Ibo gangan ni àwọn ọ̀tá wà? |
 |
 |
When exactly did you see enemy units? |
 |
 |
ee Baa wo gaH gaH nee o ree awoH eh Beh o gU o taa? |
 |
Ìgbà wo gangan ni o rí àwọn ẹgbẹ́ ogun ọ̀tá? |
 |
 |
What types of enemy units did you see? |
 |
 |
ee roo awoH eh Beh o gU o taa wo loo ree? |
 |
Irú àwọn ẹgbẹ́ ogun ọ̀tá wo l'orí? |
 |
 |
What type of equipment did the enemy units carry? |
 |
 |
ee roo awoH ohn ee jaa wo loo ree loo wo eh Beh o gU o taa? |
 |
Irú àwọn ohun ìjà wo l'orí l'ọ́wọ́ ẹgbẹ́ ogun ọ̀tá? |
 |
 |
Watch for guerilla activities. |
 |
 |
foo raa see a kee tee yaH o gU aa ba lay |
 |
Fu'ra sí akitiyan ogun abẹ́lẹ̀ |
 |
 |
Watch for conventional enemy forces. |
 |
 |
foo raa see a kee tee yaH awoH eh Beh o loo gU o taa |
 |
Fu'ra sí akitiyan àwọn ẹgbẹ́ ológun ọ̀tá |
 |
 |
Watch for enemy aircraft. |
 |
 |
foo raa see baa loo awoH eh Beh o loo gU o taa |
 |
Fu'ra sí bàálù àwọn ẹgbẹ́ ológun ọ̀tá |
 |
 |
Report to us about local inhabitants in the area. |
 |
 |
waa so fU wa nee Pa awoH aa raa aBeBe yee |
 |
Wá sọ fún wa nípa àwọn ará agbègbè yì í |
 |
 |
Set up signs to show directions and distance to TCPs. |
 |
 |
shay eh to saa bo doo laa tee so o no a tee ee bee tee sheh kee po yin tee waa |
 |
Ṣe ètò sanbọ́ọ̀dù láti sọ ọ̀nà àti ibi tí ṣẹ́kí pọnìtì TCP wà |
 |
 |
Direct refugees to refugee routes. |
 |
 |
to awoH to gU shee koo roo nee lay see o no o taa tee woh |
 |
Tọ àwọn t'ógun ṣí kúrò ní'lé sí ọ̀nà ọ̀tà ti nwọn |
 |
 |
Search the surrounding area for enemies. |
 |
 |
shay a bee wo aBeBe fU a mee awoH o taa |
 |
Ṣe àbẹ̀wò agbègbè fún àmì àwọn ọ̀tá |
 |
 |
Park the team's vehicle in a covered and safe position. |
 |
 |
paa kee awoH oo ko yE see ee bee aa bo tee ko lay woo |
 |
Páàkì àwọn ọkọ̀ yín sí ibi àbò tí kò l'ewu |
 |
 |
Set up communication with other TCP units. |
 |
 |
shay eh to ee baa nee so roo Peh loo awoH o shee sheh sheh kee po yin tee meeraH |
 |
Ṣe ètò ìbánisọ̀rọ̀ pẹ̀lú àwọn òṣìṣẹ́ ṣẹ́kí pọnìtì TCP míràn |
 |