|
Warning, United States Soldiers will be conducting a search of the area! |
|
|
ee shoora, awoH shoja ee leh amaree ka feh shay ee bay wo aBeBe yee! |
|
Ìṣọ́ra, àwọn ṣọ́jà ilẹ̀ Améríkà fẹ́ ṣe ìbẹ̀wò agbègbè yì í! |
|
|
We are looking for individuals who are planning attacks against ___ and coalition forces. |
|
|
a ohn wa awoH eh nee yo tee o ohn shay ee Be mo laatee shay awoH ___ a tee shoja wa nee jaam ba |
|
À nwá àwọn ènìyàn tí ó nṣe ìgbìmọ̀ láti ṣe àwọn ___ àti ṣọ́jà wa ní 'jàmbá |
|
|
We are looking for weapons that are being used to hurt ___ and coalition forces. Please prepare your home for inspection! |
|
|
a ohn wa awoH own ee ja tee woH ohn lo laatee shay awoH ___ a tee shoja wa nee ka. eh moora ee lay yee see leh fU a bay wo! |
|
À nwá àwọn ohun ìjà tí nwọ́n nlò láti ṣe àwọn ___ àti ṣọ́jà wa ní'kà. Ẹ múra ilé yín s'ílẹ̀ fún àbẹ̀wò! |
|
|
We are here to help the Nigerian people. |
|
|
a wa laatee raH awoH omo nay jee ree ya lo wo |
|
A wá láti ràn àwọn ọmọ Nàíjíríà l'ọ́wọ́ |
|
|
Please be advised that soldiers will not hesitate in defending themselves if threatened. |
|
|
mo feh kee eh mo we Peh awoH shoja aa Pa eh nee kay nee tee o feh shay wa nee ka |
|
Mofẹ́ kí ẹ mọ̀ wípé àwọn ṣọ́jà á pa ẹnikẹ́ni tí ó fẹ ṣe wá n'íkà |
|
|
We greatly appreciate your cooperation. |
|
|
a doo Peh gaH fU ee fo wo so wo Po reh |
|
A dúpẹ́ gan fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ rẹ |
|
|
Please open your doors. |
|
|
jo wo shee BoBo ee leh koo reh |
|
Jọ̀wọ́ ṣí gbogbo ilẹ̀kùn rẹ |
|
|
Remain outside in your yard until the search is complete. |
|
|
doroo see ee ta nee ee wa jo ee lay reh tee tee ee bay wo aa fee Pa ree |
|
Dúró sí ìta ní iwájú ilé rẹ títí Ìbẹ̀wò á fi parí |
|
|
When the soldiers arrive at your house, the homeowner can walk them through the search. |
|
|
tee awoH shoja ba day ee lay reh, o nee lay lay moo woH shay ee bay wo |
|
Tí àwọn ṣọ́jà bá dé ilé rẹ, onílé lè mú nwọn ṣe Ìbẹ̀wò |
|
|
We are not here to harm anyone. |
|
|
a ko wa laatee shay eh nee kaa nee nee ka |
|
A kò wá láti ṣe ẹnikẹ́ni n'íkà |
|
|
Our goal is to increase security in the area. |
|
|
a wa fU ee lo see wa jo ee da bo bo nee aBeBe yee |
|
A wá fún ìlọsíwájú ìdábòbò ni agbègbè yì í |
|
|
Thank you for your cooperation. |
|
|
o shay fU ee fo wo so wo Po reh |
|
O ṣé fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ rẹ |
|
|
You are permitted to have a weapon to defend your home. |
|
|
a fU eh laa yee laatee nee own ee ja fU ee da bo bo ee lay reh |
|
A fún ẹ l'áyè láti ní ohun ìjà fun ìdábòbò ilé rẹ |
|
|
The soldiers will not seize weapons used for home security if the homeowner identifies them to us before we find them. |
|
|
awoH shoja ko nee Ba awoH own ee ja tee o wa fU ee da bo bo ee lay, tee o nee lay ba fee haH wa kee a to ree woh |
|
Àwọn ṣọ́jà kò ní gba àwọn ohun ìjà tí ó wà fún ìdábòbò ilé, tí onílé bá fi hàn wá kí a tó rí nwọn |
|
|
If the soldiers find unauthorized weapons in the house or yard the homeowner will be apprehended. |
|
|
awoH shoja yo moo o nee lay tee woh ba ka awoH own ee ja tee ko wa fU ee da bo bo mo ee no ee lay ta bee leh Beh ee lay reh |
|
Àwọn ṣọ́jà yíò mú onílé tí nwọ́n bá ká àwọn ohun ìjà tí kò wà fún ìdábòbò mọ́ inú ilé tabi l'ẹ́ẹ̀gbẹ́ ilé rẹ̀ |
|