 |
Do you have information about anti-coalition activity? |
 |
 |
shay o mo nee Pa ee Be mo laatee shay wa nee ka? |
 |
Ṣé o mọ̀ nípa ìgbìmọ̀ láti ṣewá n'íkà? |
 |
 |
Please wait while I locate a translator. |
 |
 |
jo wo doroo day mee kee in lo wa o loo too mo wa |
 |
Jọ̀wọ́ dúró dèmí kí nlọ wá olùtumọ̀ wá |
 |
 |
Please come to the battalion compound to speak with Marine investigators. |
 |
 |
jo wo wa see no o Ba shoja laatee wa ba awoH shoja maa ree nee o loo wa dee soroo |
 |
Jọ̀wọ́ wá sínú ọgbà sọ́jà láti wá bá àwọn ṣọ́jà màrínì olùwádì sọ̀rọ̀ |
 |
 |
Do you know where enemy soldiers are located? |
 |
 |
shay o mo ee bee tee awoH shoja o ta wa? |
 |
Ṣé o mọ ibi tí àwọn ṣọ́jà ọ̀tá wà? |
 |
 |
Do you know where weapons are located? |
 |
 |
shay o mo ee bee tee awoH own ee ja wa? |
 |
Ṣé o mọ ibi tí àwọn ohun ìjà wà? |
 |