|
Hello, I am a United States Marine. |
|
|
en leh o, shoja maa ree nee ee leh amareeka nee mee |
|
Ẹ'nlẹ́ o, ṣọ́jà màrínì ilẹ̀ Améríkà ni mí |
|
|
May peace be upon you. |
|
|
a laa fee ya fU eh |
|
Àláfíà fún ẹ |
|
|
Please show me your identification. |
|
|
jo wo fee ee weh reh haH mee |
|
Jọ̀wọ́ fi ìwé rẹ hàn mí |
|
|
Are there any weapons in your vehicle? |
|
|
shay own ee ja wa nee no o ko reh? |
|
Ṣé ohun ìjà wà nínú ọkọ̀ rẹ? |
|
|
Is the weapon for your personal security? |
|
|
shay own ee ja no wa fU ee da bo bo reh nee? |
|
Ṣé ohun ìjà ná à wà fún ìdábòbò rẹ ni? |
|
|
Do you know that driving with a weapon in the vehicle is illegal? |
|
|
in jeh o mo Peh kee ko ohn ee ja see no o ko lo dee so fee? |
|
Njẹ́ o mọ́ pé kíkó ohun ìjà sínú ọkọ̀ lòdì sófin? |
|
|
Please show me your registration. |
|
|
jo wo fee ee weh o ko reh haH mee |
|
Jọ̀wọ́ fi ìwé ọkọ̀ rẹ hàn mí |
|
|
Please proceed slowly through the concertina wire into the search area. |
|
|
jo wo roora ko ja larE wa ya eh leh gU see ee bee ee beh wo |
|
Jọ̀wọ́ rọra kọjá l'àárín wáyà ẹlẹ́ẹ̀gún sí ibi ìbẹ̀wò |
|
|
Hello, we are United States Soldiers and will be conducting a search of your vehicle and person. |
|
|
en leh o, shoja ee leh amaree ka nee wa, a feh beh ee wo a tee ee no o ko reh wo |
|
Ẹ'nlẹ́ o, ṣọ́jà ilẹ̀ Améríkà ni wá, a fẹ́ bẹ ìwọ àti inú ọkọ̀ rẹ wò |
|
|
The goal of our checkpoint is to increase security in the area. |
|
|
ee to ee Be gee daa no yee wa fU ee lo see wa jo ee daa bo bo nee aBeBe yee |
|
Ètò ìgbégidánà yì í wà fún ìlọsíwájú ìdábòbò ni agbègbè yì í |
|
|
Please step out of the vehicle. |
|
|
jo wo bo see leh nee no o ko reh |
|
Jọ̀wọ́ bọ́ sí'lẹ̀ nínú ọkọ̀ rẹ |
|
|
Please open the doors, hood, trunk, and glove compartment. |
|
|
jo wo shee BoBo ee leh koo, boo too, en jin nee a tee beh beh lo |
|
Jọ̀wọ́ ṣí gbogbo ilẹ̀kùn, búùtù, ẹ́njìnì àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ |
|
|
Please move to the personal search area. |
|
|
jo wo lo see ee bee ee beh wo a rah |
|
Jọ̀wọ́ lọ sí ibi ìbẹ̀wò ara |
|
|
The inspection is complete. |
|
|
ee bay wo tee Paa ree |
|
Ìbẹ̀wò ti parí |
|
|
Thank you for your cooperation in making your country a safer place. |
|
|
o shay fU ee fo wo so wo Po reh fU ee da bo bo o ree leh ee dee reh |
|
O ṣé fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ rẹ fún ìdábòbò orílè èdè rẹ |
|