 |
Are you here looking for a job? |
 |
 |
shay o wa see bee laatee wa ee shay nee? |
 |
Ṣé o wá síbí láti wá iṣẹ́ ni? |
 |
 |
I'm sorry there are no jobs at this time. |
 |
 |
jo wo ko see ee shay nee a ko ko yee |
 |
Jọ̀wọ́ kò sí iṣẹ́ ní àkokò yì í |
 |
 |
The soldiers are not permitted to buy food. |
 |
 |
woH ko Ba awoH shoja laa yeh laatee ra own jeh |
 |
Nwọn kò gba àwọn ṣọ́jà láyè láti ra oúnjẹ |
 |
 |
The soldiers are not permitted to drink alcohol. |
 |
 |
woH ko Ba awoH shoja laa yeh laatee moo o tee |
 |
Nwọn kò gba àwọn ṣọ́jà láyè láti mu ọtí |
 |