|
Are you here to report a crime? |
|
|
shay o wa laatee feh jo own tee o lo dee so fey sU nee? |
|
Ṣé o wá láti f'ẹjọ́ oun tí ó lòdì sófin sùn ni? |
|
|
Were coalition forces involved? |
|
|
shay awoH shoja wa Peh lo? |
|
Ṣé àwọn ṣọ́jà wa pèlú? |
|
|
Please go to the police station to report local crimes. |
|
|
jo wo lo see a go o lo Pa laatee fay jo own tee o lo dee so fee aBeBe sU |
|
Jọ̀wọ́ lọ sí àgọ́ ọlọ́ọ̀pá láti f'ẹjọ́ oun tí ó lòdì sófin agbègbè sùn |
|