 |
Stop! |
 |
 |
doroo! |
 |
Dúró! |
 |
 |
Hands behind your head! |
 |
 |
ka wo reh sayE o ree reh! |
 |
K'áwọ́ rẹ sẹ́hìn orí rẹ! |
 |
 |
Do not move or the soldiers will kill you. |
 |
 |
doroo taabee kee awoH shoja Pa eh |
 |
Dúró tàbí kín àwọn ṣọ́jà pa ẹ́ |
 |
 |
A soldier will come to you and search you. |
 |
 |
shoja ko aa wa ba eh laatee beh eh wo |
 |
Ṣọ́jà kan á wá bá ẹ láti bẹ̀ ẹ́ wò |
 |
 |
Do not move unless told to do so. |
 |
 |
ma mee ra laa ee jeh Peh a so beh |
 |
Má mi ra láìjépé a sọ bẹ́ ẹ̀ |
 |
 |
Stay away from the vehicle. |
 |
 |
maa doroo leh Beh oko |
 |
Má à dúró l'ẹ́gbẹ ọkọ̀ |
 |
 |
If you advance further, the soldiers will kill you. |
 |
 |
tee o ba sU see wa jo see, awoH shoja aa Pa eh |
 |
Tí o bá sún síwájú sí i, àwọn ṣọ́jà á pa ẹ́ |
 |
 |
If you advance further, you will be apprehended. |
 |
 |
tee o ba sU see wa jo see, a oo moo eh see leh |
 |
Tí o bá sún síwájú sí i, a ó mú ẹ sílẹ̀ |
 |
 |
Stay away from the soldiers. |
 |
 |
maa doroo leh Beh awoH shoja |
 |
Má à dúró l'ẹ́gbẹ àwọn ṣọ́jà |
 |
 |
If you advance any closer, we will be forced to use deadly force. |
 |
 |
tee o ba sU mo wa jo, a oo shay eh nee jaam ba |
 |
Tí o bá sún mọ́ wa ju, a ó ṣè ẹ ní jàmbá |
 |
 |
The soldiers are here to help you. |
 |
 |
awoH shoja wa laatee raH eh lo wo |
 |
Àwọn ṣọ́jà wá láti ràn ẹ́ l'ọ́wọ́ |
 |
 |
We will not harm anyone that is not a threat to us. |
 |
 |
ko see eh woo fU eh nee kaa nee tee ko feh shay wa nee ka |
 |
Kò sí ewu fún ẹnikẹ́ni tí kò fẹ ṣewá n'íkà |
 |
 |
Soldiers will kill anyone who is a threat to us. |
 |
 |
awoH shoja aa Pa eh nee kaa nee tee o feh shay wa nee ka |
 |
Àwọn ṣọ́jà á pa ẹnikẹ́ni tí ó fẹ ṣewá n'íkà |
 |